Yan Yan Yan Songtext
von Zinoleesky
Yan Yan Yan Songtext
(SK on the track, SK on d track) (uh)
And the-, uhn
Back then, dem no feel us (feel us)
The way dem no take a man serious (serious)
Ask about me, we never given up
Now all my dreams, I′m living up
Now, dem dey find us like one plot for Pinnock
The way dem dey chop am like peanut
Dem be like, "Zino no go kill us"
Save us, Jesus (Jesus)
Ahn, ah, ẹmí o le yan-yan-yan
O bẹ wá, mo saare fún ní banana
O wá fẹ lọ pé mama wa oh
Ọmọ tún l'óhùn mà padà wa oh
Ah, I can′t shout (I can't shout)
No CD, mo saare lo santana
She sabi ball, o dabi Kagawa
O lẹ mi mo'ri bí tí bandana, oh
Ẹ wá, ẹ ti ẹ dúró na o
Ṣé′fẹ sọ pé ọmọ yẹn gàn o gbóná o
Ẹ má jẹkí studio yi jóná o
Ẹ má jẹkí studio yi jóná o (jona o, jona o)
L′ọwọ yi, mo ń kan'ra o
A wá l′ọmọ tí o sọnù, t'oun wa oh
Ki anybody ma f′ọwọ kàn ń kán wa oh
A wá l'ọmọ tí o sọnù, t′oun wa oh
Ṣé ẹ'mí Zino' ti o nice?
If I see something wey I like
I go wan know the price
Make my temperature dey rise (if you don′t know me)
I don′t know myself
They have no idea
What's going on in my head (what′s going on in my head)
Going on in my head
Ahn, ẹ'mí o le yan-yan-yan
O bẹ wá, mo saare fún ní banana
O wá fẹ lọ pé mama wa oh
Ọmọ tún l′óhùn mà padà wa oh
Ah, I can't shout (I can′t shout)
No CD, mo saare lo santana
She sabi ball, o dabi Kagawa
O lẹ mi mo'ri bí tí bandana, oh
Ẹ wá, ẹ ti ẹ dúró na o
Ṣé'fẹ sọ pé ọmọ yẹn gàn gbóná o
Ẹ má jẹkí studio yi jóná o
Ẹ má jẹkí studio yi jóná o
L′ọwọ yi, mo ń kan′ra o
A wá l'ọmọ tí o sọnù, t′oun wa oh
Ki anybody ma f'ọwọ kàn ń kán wa oh
A wá l′ọmọ tí o sọnù, t'oun wa oh
(Dúró na o)
(Ṣé′fẹ sọ pé ọmọ yẹn gàn gbóná o)
(Ẹ má jẹ'kí studio yi jóná o)
(Ẹ má jẹ'kí studio yi jóná o)
(L′ọ′wọ yi, mo ń-)
(SK, SK, SK-)
(Boombah)
And the-, uhn
Back then, dem no feel us (feel us)
The way dem no take a man serious (serious)
Ask about me, we never given up
Now all my dreams, I′m living up
Now, dem dey find us like one plot for Pinnock
The way dem dey chop am like peanut
Dem be like, "Zino no go kill us"
Save us, Jesus (Jesus)
Ahn, ah, ẹmí o le yan-yan-yan
O bẹ wá, mo saare fún ní banana
O wá fẹ lọ pé mama wa oh
Ọmọ tún l'óhùn mà padà wa oh
Ah, I can′t shout (I can't shout)
No CD, mo saare lo santana
She sabi ball, o dabi Kagawa
O lẹ mi mo'ri bí tí bandana, oh
Ẹ wá, ẹ ti ẹ dúró na o
Ṣé′fẹ sọ pé ọmọ yẹn gàn o gbóná o
Ẹ má jẹkí studio yi jóná o
Ẹ má jẹkí studio yi jóná o (jona o, jona o)
L′ọwọ yi, mo ń kan'ra o
A wá l′ọmọ tí o sọnù, t'oun wa oh
Ki anybody ma f′ọwọ kàn ń kán wa oh
A wá l'ọmọ tí o sọnù, t′oun wa oh
Ṣé ẹ'mí Zino' ti o nice?
If I see something wey I like
I go wan know the price
Make my temperature dey rise (if you don′t know me)
I don′t know myself
They have no idea
What's going on in my head (what′s going on in my head)
Going on in my head
Ahn, ẹ'mí o le yan-yan-yan
O bẹ wá, mo saare fún ní banana
O wá fẹ lọ pé mama wa oh
Ọmọ tún l′óhùn mà padà wa oh
Ah, I can't shout (I can′t shout)
No CD, mo saare lo santana
She sabi ball, o dabi Kagawa
O lẹ mi mo'ri bí tí bandana, oh
Ẹ wá, ẹ ti ẹ dúró na o
Ṣé'fẹ sọ pé ọmọ yẹn gàn gbóná o
Ẹ má jẹkí studio yi jóná o
Ẹ má jẹkí studio yi jóná o
L′ọwọ yi, mo ń kan′ra o
A wá l'ọmọ tí o sọnù, t′oun wa oh
Ki anybody ma f'ọwọ kàn ń kán wa oh
A wá l′ọmọ tí o sọnù, t'oun wa oh
(Dúró na o)
(Ṣé′fẹ sọ pé ọmọ yẹn gàn gbóná o)
(Ẹ má jẹ'kí studio yi jóná o)
(Ẹ má jẹ'kí studio yi jóná o)
(L′ọ′wọ yi, mo ń-)
(SK, SK, SK-)
(Boombah)
Writer(s): Peter Mwangi Mwitii, Azeez Shina Oniyide Lyrics powered by www.musixmatch.com