Agba Lo De Songtext
von Tunji Oyelana
Agba Lo De Songtext
Agba lo de mo mi nfe sọ rin
Agba ló de mo mi nfe sọ rin
Ẹ má pé mo pe o oni moto ni o
Gba mi agba lo de mo mi nfe sọ rin
Oni moto gbe mi yee ogbó ki se efe
Oni moto gbé mi yà ogbo ki ise iya
Oni moto ṣe mi jeeje mo lowo mi lapo
Agba ló de mo mi nfe sọ rin
Ẹ má pé mo pe o oni moto ni o
Gba mi agba lo de mo mi nfe sọ rin
Oni moto gbe mi yee ogbó ki se efe
Oni moto gbé mi yà ogbo ki ise iya
Oni moto ṣe mi jeeje mo lowo mi lapo
Writer(s): Tunji Oyelana Lyrics powered by www.musixmatch.com