Songtexte.com Drucklogo

Sijuade Songtext
von King Sunny Adé

Sijuade Songtext

Sijuade ma re o
Ooni ile ife

Sijuade re o
Ooni ile ife

Adimula mo se ba
Ohun o wi wa fun mi mo magbagbe
Oni bati wi ti Oba pe
Awowo awo

Adimula mo se ba
Oun owi wa fun mi mo magbagbe
Oni bati wi ti Oba pe
Awowo awo o


Adimula mo se ba o
Oun o wi wa fun mi mo magbagbe
Oni bati wi ti Oba pe
Awowo awo
Awowo awo ye ni m′ole
Awowo awo
Awowo awo ye ni m'ole
Awowo awo

Oni bati wi ti Oba pe
Awowo awo
Oni bati wi ti Oba pe
Awowo awo
Awowo awo ye ni m′ole
Awowo awo

Oni bati wi ti Oba pe
Awowo awo
Awowo awo ye ni m'ole
Awowo awo
Oni bati wi ti Oba pe
Awowo awo
Adimula mo se ba
Oun owi wa fun mi mo magbagbe
Oni bati wi ti Oba pe awowo awo

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von King Sunny Adé

Fans

»Sijuade« gefällt bisher niemandem.