Omode O'Mela Songtext
von King Sunny Adé
Omode O'Mela Songtext
Wọni ọmọde o Mela
Olohun Mela katakata
Wọni ọmọde o Mela
Olohun Mela katakata
Lai Mope èlà katakata ọba ija ni
Ore, kaso aja mole, kaso ẹkun mole
Ti aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowo
Kilefiri ni sí oyi bwag eyi ga Lọlá
Koye won rara
Bwag eyi ga Lọlá
Koyewon rara
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Sunny Ade ode bi otin dé
Kaso aja mole, kaso ẹkun mole
Ti aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowo
Kilefiri ni sí oyi bwag eyi ga Lọla
Koyewon rara
Eyi bu wa eyi ga lola
Koyewon rara
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Sunny Ade ode bi otin dé
Ọpọlọ ye eyin o fi eyin pamo kilon fi pamo fún
Alangba yẹ eyin o fi pamo, kilon fi pamo fún
Igun yẹ eyin, o fi eyin pamo, kilon fi pamo fún
Igun ti o wa yẹ eyin to tun wa feyin pamo
Ati igun ati eyin rẹ, won o ṣe sebe je
Bi wọn ki wa gun lo
Bi wọn ki wa gun tete
Bi wọn ki wa gun lo
Bi wọn ki wa gun tete
Iho iho ni akara wa ti moi moi ti n ṣe oge
Ewé omo ogbon ṣe jube lo, omo logbe
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Ewé kín gbo
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Igba ti o ṣe tiwon, o sọ sí rárá
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Àwa ṣe tiwa won pon ju koko
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Ojú tó pọ koko kole tun lo sa morore
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Kingbo
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Ojumo
Olohun Mela katakata
Wọni ọmọde o Mela
Olohun Mela katakata
Lai Mope èlà katakata ọba ija ni
Ore, kaso aja mole, kaso ẹkun mole
Ti aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowo
Kilefiri ni sí oyi bwag eyi ga Lọlá
Koye won rara
Bwag eyi ga Lọlá
Koyewon rara
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Sunny Ade ode bi otin dé
Kaso aja mole, kaso ẹkun mole
Ti aba fi iru ekùn ka fi lè aja lowo
Kilefiri ni sí oyi bwag eyi ga Lọla
Koyewon rara
Eyi bu wa eyi ga lola
Koyewon rara
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Ọlọgbọn lọ mi ayé, awọn omoran a mọdi
Sunny Ade ode bi otin dé
Ọpọlọ ye eyin o fi eyin pamo kilon fi pamo fún
Alangba yẹ eyin o fi pamo, kilon fi pamo fún
Igun yẹ eyin, o fi eyin pamo, kilon fi pamo fún
Igun ti o wa yẹ eyin to tun wa feyin pamo
Ati igun ati eyin rẹ, won o ṣe sebe je
Bi wọn ki wa gun lo
Bi wọn ki wa gun tete
Bi wọn ki wa gun lo
Bi wọn ki wa gun tete
Iho iho ni akara wa ti moi moi ti n ṣe oge
Ewé omo ogbon ṣe jube lo, omo logbe
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Ewé kín gbo
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Igba ti o ṣe tiwon, o sọ sí rárá
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Àwa ṣe tiwa won pon ju koko
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Ojú tó pọ koko kole tun lo sa morore
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Kingbo
Afefe yeye komai ṣe afefe yeye síwá mo
Ojumo
Writer(s): King Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com