Songtexte.com Drucklogo

Ode le Alaga Songtext
von King Sunny Adé

Ode le Alaga Songtext

Ode Le alaga, ode Le alaga
Oyele mori re, oyele mori re wale
Ode Le alaga, ode Le alaga
Oyele mori re, oyele mori re
Ode Le alaga, ode Le alaga
Oyele mori re, oyele mori re wale
Ode Le alaga, ode Le alaga
Oyele mori re, oyele mori re


Ọba ma fi mi bin se wa rẹ mi eyin are ololoriwo
Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun
Igbeyin lodun a haa, Igbeyin lodun a haa
Tori alase bimo o, Igbeyin lodun
Oluwa Maje ki a de lale
YeYe alala kí ọtọ bi mo re, igbeyin lo mo ju o jàre
Baba ọlọrun kì é to mo re, igbeyin lo mo ju o jàre
Tori
Ọba ma fi mi bin se wa rẹ mi eyin are ololoriwo
Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun
Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun
Tori ala lase bimo o, Igbeyin lodun
Oluwa Maje ki a de lale

Oluwa Maje ka dé o jàre
Oluwa Maje ka dé lale
Igbeyin lo dun ara ayé o
Oluwa Maje ka dé lale
Igbeyin lo mo dun kí ọtọ bi mo yin lo jàre
Oluwa Maje ka dé lale
Iya ọlọmọ toju omo rẹ

Igbeyin lodun a haa Igbeyin lodun
Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun
Tori alase bimo o, Igbeyin lodun
Oluwa Maje ki a de lale

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von King Sunny Adé

Quiz
Wer ist kein deutscher Rapper?

Fans

»Ode le Alaga« gefällt bisher niemandem.