Mo Beru Agba Songtext
von King Sunny Adé
Mo Beru Agba Songtext
Mo beru aagba (mo beru agba, mo beru agba o)
A i beru agba ni o jaiye o gun
Elegbe moni mo beru agba
Agba n′bowa kan e o ee
Agba n'bowa kan e o o laiye nbi
Agba n′bowa kan e o e
Aye o o o (Aye o Aye o e)
Oṣika, ranti ojo atisun re o e
Iwo odale, ranti ojo atisun re o e
Eni s'ebi (ibi lo mi a j'ere fun)
Eni ba se ka nko o
Ika lo mi a j′ere fun
Bo ba wun e ko s′ere
Ire lo mi a j'ere re
Bo wun e ko se ka
Ika lo mi a j′ere re
Bofe bofe
Esan a ke lori e
Bode bofe
Esan a ke lori e
Odale se o ngbo (esan a ke lori re)
Nje mo d'ifa titi mo mu re ko ifa
No da da mo mu re ′di ope
Nje mo d'ifa titi mo mu re ko ifa
No da da mo mu re ′di ope
Ope mi ti ti mo se b'ojo lo ro
Ojo pami lapa kan lapa kan mi
Ojo pa mi o mase p'oremi
Ah agbo ′ba mi digi ogi
Tio loko tiolo
Agbo ′ba mi digi ogi
Tio loko tiolo
Rasaki ijo ti ya o
Tio loko tiolo
Agbo 'ba mi digi ogi
Tio loko tiolo
A i beru agba ni o jaiye o gun
Elegbe moni mo beru agba
Agba n′bowa kan e o ee
Agba n'bowa kan e o o laiye nbi
Agba n′bowa kan e o e
Aye o o o (Aye o Aye o e)
Oṣika, ranti ojo atisun re o e
Iwo odale, ranti ojo atisun re o e
Eni s'ebi (ibi lo mi a j'ere fun)
Eni ba se ka nko o
Ika lo mi a j′ere fun
Bo ba wun e ko s′ere
Ire lo mi a j'ere re
Bo wun e ko se ka
Ika lo mi a j′ere re
Bofe bofe
Esan a ke lori e
Bode bofe
Esan a ke lori e
Odale se o ngbo (esan a ke lori re)
Nje mo d'ifa titi mo mu re ko ifa
No da da mo mu re ′di ope
Nje mo d'ifa titi mo mu re ko ifa
No da da mo mu re ′di ope
Ope mi ti ti mo se b'ojo lo ro
Ojo pami lapa kan lapa kan mi
Ojo pa mi o mase p'oremi
Ah agbo ′ba mi digi ogi
Tio loko tiolo
Agbo ′ba mi digi ogi
Tio loko tiolo
Rasaki ijo ti ya o
Tio loko tiolo
Agbo 'ba mi digi ogi
Tio loko tiolo
Writer(s): King Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com