Ma Jaiye Oni Songtext
von King Sunny Adé
Ma Jaiye Oni Songtext
Ma j′aye oni o
Mi o m'eyin ola o
Ma j′aye oni o
Mi o m'eyin ola o
Iba akoda to da ti e s'ori ewe
Iba akoda to da ti e s′ori ewe
Iba aseda to da ti e s′ile iyepe
Iba aseda to da ti e s'ile iyepe
Iba atete ko d′aye to da ti e s'ofurufu
Iba atete ko d′aye to da ti e s'ofurufu
Mo se iba araye e je ki n j′aye ori mi
Ma j'aye oni o
Mi o m'eyin ola o
Ma j′aye oni o
Mi o m′eyin ola o
Mi o m'eyin ola o
Ma j′aye oni o
Mi o m'eyin ola o
Iba akoda to da ti e s'ori ewe
Iba akoda to da ti e s′ori ewe
Iba aseda to da ti e s′ile iyepe
Iba aseda to da ti e s'ile iyepe
Iba atete ko d′aye to da ti e s'ofurufu
Iba atete ko d′aye to da ti e s'ofurufu
Mo se iba araye e je ki n j′aye ori mi
Ma j'aye oni o
Mi o m'eyin ola o
Ma j′aye oni o
Mi o m′eyin ola o
Writer(s): King Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com