Ko Salapata Songtext
von King Sunny Adé
Ko Salapata Songtext
Oluwa nbe l′oke fun gbogbo wa
Edumaare ko saanu fun wa
Eni ba gbeke le Oluwa
Ko ma ni jogun r'ofo
Oluwa nbe
K′eru ma se ba wa
Hunhunhun elede inu r'elede lo n gbe
Eni t'Olorun ko ba pa o
Koma seni to le pa
Komasa, komasa
Komasalapata
To gbodo pa igun je
Eewo! aja ko gbodo jobi
Aki binu ori, ti fila de ba di
Komasa, komasa
Koma s′alapata
To gbodo pa igun je
Eewo! Aja ko gbodo jobi
Aki binu ori, ti fila de ba di
Komasa, komasa
Koma s′alapata
To gbodo pa igun je
Eewo! Aja ko gbodo jobi
Aki binu ori, ti fila de ba di
Edumaare ko saanu fun wa
Eni ba gbeke le Oluwa
Ko ma ni jogun r'ofo
Oluwa nbe
K′eru ma se ba wa
Hunhunhun elede inu r'elede lo n gbe
Eni t'Olorun ko ba pa o
Koma seni to le pa
Komasa, komasa
Komasalapata
To gbodo pa igun je
Eewo! aja ko gbodo jobi
Aki binu ori, ti fila de ba di
Komasa, komasa
Koma s′alapata
To gbodo pa igun je
Eewo! Aja ko gbodo jobi
Aki binu ori, ti fila de ba di
Komasa, komasa
Koma s′alapata
To gbodo pa igun je
Eewo! Aja ko gbodo jobi
Aki binu ori, ti fila de ba di
Writer(s): King Sunny Adé Lyrics powered by www.musixmatch.com