John Ali Songtext
von King Sunny Adé
John Ali Songtext
Mi o le gbagbe re
Ni′bi ki'bi t′owu k'owa omo Ali
Ayanfe omo rere
Ali, Ali, Ali
Abiodun mi, omo Ali o
Edumare fun e ni moni lo l'aye
Abiodun o, omo Ali mi
Oba oke fun e ni moni lo jaburata
Ali, Ali, Ali
Ali, Ali, Ali
Abiodun o, omo Ali mi
Edumare fun e ni moni lo l′aye
Abiodun o, omo Ali mi
Oba oke fun e ni moni lo jabura
Omo Abiodun Ali mi o ire
Omo Abiodun Ali mi o ire
Oko oredola bi director ba n so
Ire, omo Abiodun Ali mi o ire
Oko Adebisi oyinbo onisowo
Ire, omo Abiodun Ali mi o ire
Oko Funlola oyinbo peace way
Ire, omo Abiodun Ali mi o ire
Baba Sola
Ire, omo Abiodun Ali mi o ire
Ni′bi ki'bi t′owu k'owa omo Ali
Ayanfe omo rere
Ali, Ali, Ali
Abiodun mi, omo Ali o
Edumare fun e ni moni lo l'aye
Abiodun o, omo Ali mi
Oba oke fun e ni moni lo jaburata
Ali, Ali, Ali
Ali, Ali, Ali
Abiodun o, omo Ali mi
Edumare fun e ni moni lo l′aye
Abiodun o, omo Ali mi
Oba oke fun e ni moni lo jabura
Omo Abiodun Ali mi o ire
Omo Abiodun Ali mi o ire
Oko oredola bi director ba n so
Ire, omo Abiodun Ali mi o ire
Oko Adebisi oyinbo onisowo
Ire, omo Abiodun Ali mi o ire
Oko Funlola oyinbo peace way
Ire, omo Abiodun Ali mi o ire
Baba Sola
Ire, omo Abiodun Ali mi o ire
Writer(s): Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com