Songtexte.com Drucklogo

Ibanuje Mon Iwon Songtext
von King Sunny Adé

Ibanuje Mon Iwon Songtext

Ibanuje mon niwon
Feni tori ba ri wa mu

Ibanuje mon niwon
Feni tori ba ri wa mu

Taba yowo ebi somori tewe tagba
Ise ku ferefere

Taba yowo tebi somori tewe tagba
Ise ku ferefere

Oba to da oni kaluku
Lomo ohun to ma je

Oba to da oni kaluku
Lomo ohun to ma je

Gara di e da po ju o
Nitori owo

Gara di e da po ju o
Nitori owo

Ohun ti o so nu
Ti gbogbo wa wa kiri


Ohun ti o so nu
Ti gbogbo wa wa ki
Taba firi ke ohun eledumare ni
Taba firi o ohun eledumare ni
Nitemi, bi moti sori
Owo nini kogba gbara o
Gbogbo re riro ni temi
Asiko laye
Eni to ba hun eledumare lole de lade owo

Fiwa lokan bale
Oba to laye
Fiwa lokan bale
Oba to laye
Ka fi ra wa lokan bale
Kaye fipa wo wo
Kafi ra wa lokan bale
kaye fipa wo wo

Fiwa lokan bale
Oba to laye
Kafi ra wa lokan bale
Kaye fipa wo wo

Ato lowo ati tanika
Gbogbo lo mi a ku
Bolowo ti gba dun na, ko bi mo bi eja
Oniwa loni lo lorun asanke


Jah jehova oba onibu ore
Jah jehova oluwa ko pin kari
Jah jehova oluwa ko pin kari
Owo pelu omo pelu alafia
Jah jehova oluwa ko pin kari

Ma farun tiwa mole
Ma fi le wa jade
Ma farun tiwa mole
Ma fi le wa jade
Ma farun le wa jade
Mafi tiwa mole
Somori tewe tagba
Kajo gba dun nu kale
Jah jehova kolu wa ko pin kari

Jah jehova oba oluwa ko pin kari
Jah jehova oluwa kopin kari
Jah jehova oluwa kopin kari
Owo omo pelu alaafia pelu iyin ara
Jah jehova oluwa kopin karil

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von King Sunny Adé

Quiz
Welcher Song ist nicht von Robbie Williams?

Fans

»Ibanuje Mon Iwon« gefällt bisher niemandem.