Dele Davis Songtext
von King Sunny Adé
Dele Davis Songtext
Baba wa olu orun
Baba wa Ja Jehovah o
J′owo ma ma je a m'osi
Sin wa de ile ola
Baba wa olu orun
Baba wa Ja Jehovah o
J′owo ma ma je ka m'osi
Sin wa de ile ola
Baba wa olu orun
Baba wa Ja Jehovah o
J'owo ma ma je a m′osi
Sin wa de ile ola
Emi k′ole gbagbe Mose Orimolade (Orimolade)
Emi k'ole gbagbe Mose (Orimolade)
O ti kekere m′oju Oluwa (Orimolade)
O d'agbalagba sinu imole (Orimolade)
Awa k′ole sai sope (Baba wa l'oke)
(Baba wa l′oke), (Baba wa l'oke)
Baba wa Ja Jehovah o
J′owo ma ma je a m'osi
Sin wa de ile ola
Baba wa olu orun
Baba wa Ja Jehovah o
J′owo ma ma je ka m'osi
Sin wa de ile ola
Baba wa olu orun
Baba wa Ja Jehovah o
J'owo ma ma je a m′osi
Sin wa de ile ola
Emi k′ole gbagbe Mose Orimolade (Orimolade)
Emi k'ole gbagbe Mose (Orimolade)
O ti kekere m′oju Oluwa (Orimolade)
O d'agbalagba sinu imole (Orimolade)
Awa k′ole sai sope (Baba wa l'oke)
(Baba wa l′oke), (Baba wa l'oke)
Writer(s): King Sunny Adé Lyrics powered by www.musixmatch.com