Bombibele Horojo Songtext
von King Sunny Adé
Bombibele Horojo Songtext
B′oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele ba n bi′nu, alabaja a nawo gan ni Alade ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B′oni pele ba n bi′nu, alabaja a fa mora ni
African beat tun gbede, ori o gbodo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele ba n bi′nu, alabaja a nawo gan ni Alade ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B′oni pele ba n bi′nu, alabaja a fa mora ni
African beat tun gbede, ori o gbodo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
Writer(s): King Sunny Adé Lyrics powered by www.musixmatch.com