Songtexte.com Drucklogo

Ara Ma Nfe Sinmi Songtext
von King Sunny Adé

Ara Ma Nfe Sinmi Songtext

Ọrẹ rẹ die bínú bínú woni mo ku
Iya gbó ni lè ebi ń wá ní kiri
Iya gbó ni lè ọrẹ ń wá ní kiri
Tebi Tara tore, won temi lago
Lai mo wípé
Mi ò báwọn wá, ẹ mi ò ní báwọn lo
Mi ò báwọn wá, ẹ mi ò ní báwọn lo
Ototo larin wá, Ototo larin wá
Ṣebi ile ayé, ilé ayé, ilé ayé yí là pàdé ara wa
Ọrẹ wá, ọjọ′ lọ npe ó, Ìpàdé kìí jinna
ọjọ' lọ npe ó, Ìpàdé kìí jinna
Ìkà eda tó fowo padà Ọlọ′run loju
Ìkà eda tó fowo padà Ọlọ'run loju
Ìdájọ' ó jìnnà, idajo ó jìnnà
Aye ẹ má dalekun
Torí mi ò báwọn wá, èmi ò ní báwọn lo
Mi ò báwọn wá, èmi ó ní báwọn lo
Torí, òtoto larin wa, òtoto larin wá
Ṣebi ile ayé, ilé ayé, ilé ayé yí là pàdé ara wa


Ayéeeeeeee, Ayee yiii oooo
Ayéeeeeeee, Ayee yiii oooo
Ayé toto
Ọjọ′ ó rò, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo
Ọjọ′ ó rò, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo
Ọjọ' ó rò se, ìṣù ó tà, àgbàdo ó gbó oo
Ara máa ń fẹ′, (ara máa ń fẹ' simi)
E rọra ṣe (ara máa ń fẹ′ simi)
E rọra (ara máa ń fẹ' simi)
Ara máa ń fẹẹ (ara máa ń fẹ′ simi)
Àní ara máa ń fẹ' ó jare (ara máa ń fẹ' simi)
Jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ′ simi)
Ọrẹ wá jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ′ simi)
Ifakafiki làálàá lè (ara máa ń fẹ' simi)
Jìgìjìgì lojojumo (ara máa ń fẹ′ simi)
Ará máa ń fẹ' ó jare (ara máa ń fẹ′ simi)
Ifakafiki lórí ẹni (ara máa ń fẹ' simi)
Ará máa ń fẹ′ (ara máa ń fẹ' simi)
(End.)

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von King Sunny Adé

Quiz
Wer ist gemeint mit „The King of Pop“?

Fans

»Ara Ma Nfe Sinmi« gefällt bisher niemandem.