Songtexte.com Drucklogo

Adena Ike Songtext
von King Sunny Adé

Adena Ike Songtext

Oro gbogbo lori owo, yes otito ni
A′i si owo baba ijaya, yes otito ni
A l'owo lowo baba ifokanbale, yes otito ni
A l′owo lowo baba afojudi, yes otito ni
Bi a ba l'owo lowo la n da'moran nla, yes otito ni
Adenaike currency controller, yes otito ni

Oyinbo ile owo ni, oyinbo ile owo o
Adenaike, oyinbo ile owo o
Gboyega, oyinbo ile owo o
Baba Gbenga, oyinbo ile owo o
Oko Funke, oyinbo ile owo o
Ijebu Omu maa ba lo, oyinbo ile owo o
Toba digba owuro, ka fi gbele pa′wo
Toba digba owuro sir, ka fi gbele pa′wo
Ka na'wo funfun, ka na′wo pupa, kawa da lari bora


Igba laye ooo
N ba lowo n ba yo, oyinbo ile owo o
O tun gbe tuntun de, ololu
Currency controller mi, ololu
Gboyega Adenaike, ololu
Olowo gboye meji po, ololu

Ma ya'na ma lo sodo padi mi Nurudeeni omo Animasahun
Omo Animasahun, omo Animasahun
Omo Animasahun, omo Animasahun
Nurudeen omo Animasahun
The barrister omo Animasahun
Managing director, omo Animasahun
Oko alhaja, omo Animasahun
Nurudeen, omo Animasahun

Ma fi′ya je o, oba oluwa ma fi'ya je o
Ma fi′ya je o, oba oluwa ma fi'ya je o
Oluwa ma fi'ya je omo Animasahun, ma fi′ya je o
Ma fi′ya je o, oba oluwa ma fi'ya je o
Ma fi′ya je, oba oluwa ma fi'ya je o
Oluwa ma fi′ya je omo Animasahun, ma fi'ya je o
Nurudeen omo toba be, ma fi′ya je o
Oko alhaja mi, ma fi'ya je o
Oluwa ma fi'ya je omo Animasahun, ma fi′ya je o


Odi ile Ayo Sasanya mi, oyinbo oni sowo
Ayo Sasanya, oyinbo oni sowo
Ayo Sasanya, oyinbo oni sowo
Ayo Sasanya, oba je o gbadun laye
Ko rere oja je
Ko sowo ko jere, ko rere oja je
Ki′wo ma padanu nile aye re
Ko olori buruku ko ma maa koba e
Amin o ase o, Ayo Sasanya

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von King Sunny Adé

Quiz
Wer singt das Lied „Haus am See“?

Fans

»Adena Ike« gefällt bisher niemandem.